Share to: share facebook share twitter share wa share telegram print page

Windhoek Public Library

Windhoek Public Library jẹ́ ilẹ̀ ìkàwé kan ní downtown Windhoek, orílẹ̀ èdè Namibia. Wọ́n kọ ní ọdún 1925, ó sì wà ní Lüderitz Street, nínú ilé kan náà tí Owela strand wà ní National Museum ti Namibia.[1] Láàrin oṣù kejì 2009 sí oṣù kẹjọ ọdún 2012,[2] wọ́n ṣe àtúnṣe tí ó gbà tó iye owó N$ 700,000, àwọn àtúnṣe yìí ni àwọn iṣẹ́ bi lí lo amúlétutù, fí fi àwọn iná mọ̀nà mọ́ná, àti fí fi ojú ẹ̀rọ ayélujára síbè.[3]

Àwọn Ìtọ́kasí

  1. Hillebrecht, Werner (2012). "The National Archives of Namibia". Namibia Library and Archives Service Information Bulletin (Government of Namibia) (1): 4–6. ISSN 2026-707X. Archived from the original on 2023-04-08. https://web.archive.org/web/20230408175835/http://www.nln.gov.na:8081/custom/web/content/2012%20newsletter.pdf. Retrieved 2023-05-07. 
  2. Mukaiwa, Martha (28 September 2012). "The return of the Windhoek public library". The Namibian: p. 1. Archived from the original on 29 November 2021. https://web.archive.org/web/20211129070639/https://www.namibian.com.na/index.php?page=archive-read&id=100558. 
  3. Shejavali, Nangula (19 February 2009). "Public library gets a facelift". The Namibian: p. 1. Archived from the original on 29 November 2021. https://web.archive.org/web/20211129070640/https://www.namibian.com.na/50749/archive-read/Public-library-gets-a-facelift-BAD-news-for. 
Prefix: a b c d e f g h i j k l m n o p q r s t u v w x y z 0 1 2 3 4 5 6 7 8 9

Portal di Ensiklopedia Dunia

Kembali kehalaman sebelumnya