The Source (fiimu 2011)
The Source (Ni Yoruba: orisun ) je eré-apanilẹrin ti Radu Mihăileanu daari, Leïla Bekhti ati Hafsia Herzikopa ninu ere na. O ṣe afihan ni Idije Cannes Film Festival.[1] to odun 2011. Ahunpo ItanṢeto ni abule ti o jina ni Ariwa Afirika, itan naa da lori awọn obinrin ti pinu pe awon yan ibalopo loodi ote won looru laati lo pon omi lati kanga ti o jina. Itan naa jẹ aṣamubadọgba ti awada Greek atijọ Lysistrata. Awon Osere![]()
ṢiṣejadeA ṣe fiimu naa nipasẹ awon fiimu France's Elzevir ati Oï Oï Oï Productions, ni iṣelọpọ pẹlu France 3 Cinéma ati EuropaCorp. Yaato si idoko-owo Faranse 64% , awọn ile-iṣẹ lati ilu Belijiomu ṣe idasi 14%, Ilu Italia 12% ati Moroccan 10%. Canal+ and CinéCinéma ti ra kaale ode tun rri atilẹyin lati odo awon Eurimages. Lapapọ isuna jẹ ku die ko je milionu meejo owo awọn owo ilẹ yuropu.[2] IgbejaadeThe Source ṣe afihan ni ni Idije Cannes Film Festival.[1]ni osu kaarun odun 2011. May. [3] Ipinpin EuropaCorp ṣe idasilẹ ni Ilu Faranse ni ọjọ 2 Oṣu kọkanla ọdun 2011. Awọn iyin
Awọn itọkasi
|