Share to: share facebook share twitter share wa share telegram print page

Setonji David

Honourable

Setonji Samuel David
Member and Chief Whip of the Lagos State House of Assembly
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
2015
ConstituencyBadagry II
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí12 Oṣù Kejìlá 1959 (1959-12-12) (ọmọ ọdún 65)
Lagos
Ọmọorílẹ̀-èdèNigerian
Ẹgbẹ́ olóṣèlúAll Progressives Congress (APC)
OccupationPolitician

Setonji David ( a bí i ní ọjọ́ kejìlá, oṣù kejìlá, ọdún 1959 (12 December 1959))[1] ó jẹ́ olóṣèlú ọmọ bíbí orílẹ-èdèNàìjíríà àti pé òun ni ó jẹ́ agbọ́pàá ní ilé ìgbìmọ̀ àwọn aṣojsòfin ti Ìpínlẹ̀ Èkó,ó ń ṣojú ẹkùn ìdìbò kejì ti agbègbè Badagry láti ọdún 2015.[2][3][4][5][6][7][8] Ó ti fi ìgbà kan rí jẹ́ alága ìgbìmọ̀ ilé lórí ètò àyíká àti ìdàgbàsókè ìlú.[9]

Àwọn ìtọ́kasí

  1. Lagos, Lshaa (2024-04-25). "Deputy Chief Whip (Hon. Engr. Setonji S. David)". Lagos House Of Assembly. Retrieved 2024-12-07. 
  2. Ewodage, Rejoice (2024-08-05). "Legislative profile: Setonji David". Ikeja Record. Retrieved 2024-12-07. 
  3. "Lagos lawmaker loses wife after brief illness". Pulse Nigeria. 2024-05-25. Retrieved 2024-12-07. 
  4. "Lagos lawmaker loses wife". Peoples Gazette Nigeria. 2024-05-25. Retrieved 2024-12-07. 
  5. "Reconstruct Lagos-Badagry-Seme Expressway, lawmaker to Buhari". The Nation Newspaper. 2018-10-24. Retrieved 2024-12-07. 
  6. "2023: Lawmaker begs APC to adopt Tinubu as consensus candidate". Premium Times Nigeria. Retrieved 2024-12-07. 
  7. "Lagos-Badagry expressway a 'national embarrassment' — Lawmaker". Premium Times Nigeria. Retrieved 2024-12-07. 
  8. Muaz, Hassan (2023-08-06). "Lagos lawmaker commiserates with Senator Adeola over aide's death". The Eagle Online. Retrieved 2024-12-07. 
  9. "Building collapse: Assembly to go after regulatory agencies". The Nation Newspaper. 2017-06-05. Retrieved 2024-12-07. 
Prefix: a b c d e f g h i j k l m n o p q r s t u v w x y z 0 1 2 3 4 5 6 7 8 9

Portal di Ensiklopedia Dunia

Kembali kehalaman sebelumnya