Share to: share facebook share twitter share wa share telegram print page

Public university

With 79,232 students as of the 2022-23 academic year, Arizona State University in Tempe, Arizona is the largest public university in the United States.

Public university tàbí Yunifásítì ti Ìjọba jẹ́ university (Ilé-ẹ̀kọ́ ) tí ó jẹ́ ti ìjọba tàbí tí ó ń gba owó láti ọ̀dọọ ìjọba. Ilé ẹ̀kọ́ tí ó bá jé tí ìjọba àpapọ̀, àwọn orílẹ̀ èdè kan máa ń pèníní ilé ẹ̀kọ́ ìjọba. Àwọn mìíràn kí síi pè bẹ̀. Ìdà kejì rẹ̀ ni private university (ilé ẹ̀kọ́ gíga aladani) máa ń jẹ́ tí ẹnì kan pàtó àbí àwọn ìjọ ẹ̀yán kan(wọ́n lè ma jẹ èrè níbè àbí kí wọ́n má jẹ). Àwọn méjèèjì náà ni ìjọba máa ń mójú tó ṣùgbọ́n ju ara wọn lọ.

Prefix: a b c d e f g h i j k l m n o p q r s t u v w x y z 0 1 2 3 4 5 6 7 8 9

Portal di Ensiklopedia Dunia

Kembali kehalaman sebelumnya