Pascal Aka (tí wọ́n bí ní Ivory Coast, ní ọjọ́ kẹtàdínlógún oṣù keje, ọdún 1985) jẹ́ olùdarí fíìmù ti Ivory Coast, òṣèré, olùdarí fídíò orin àti olùṣàgbéjáde fíìmù,[2][3] tó gba júmọ̀ fún iṣẹ́ rẹ̀ lórí "Jamie and Eddie: Souls of Strife (2007)",[4] "Evol (2010)",[5]Double-Cross èyí tó gba ọ̀pọ̀lọpọ̀ àmì-ẹ̀yẹ ní Ghana Movies Award 2014.[6][7][8]
Iṣẹ́ rẹ̀
Ìlú Abidjan, ní Ivory Coast ni wọ́n bi sí, àmọ́ Ghana ni Pascal Aka sì dàgbà sí.[9] Ó lọ sí University of Carleton níbi tí ó ti kẹ́kọ̀ọ́ nípa " film studies program" ó sì tún fìgbà kan jẹ́ ọmọ ìkọ́ṣẹ́ ní Independent Filmmaker's Cooperative ti Ottawa, níbi tí ó ti ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí i Olùdarí àgbà, Alága ìgbìmọ̀ àti Igbákeji Ààrẹ. Ó ṣe àgbájáde fíìmù àkọ́kọ́ rẹ, ìyẹn "Jamie and Eddie: Souls of Strife" èyí tí ó gbé jáde, jẹ́ olùdarí fún, tí ó sì tún kópa nínú, nígbà tí ó wà ní ọmọdún mọ́kànlélógún. Lẹ́yìn ọdún mẹ́sàn-án ní Canada, Pascal padà lọ sí Ghana láti bẹ̀rẹ̀ ilé-iṣẹ́ tirẹ̀, èyí tí ó sọ ní "Breakthrough Media Productions".[10][11]
Àwọn fíìmù rẹ̀
Year
|
Film
|
Role
|
2007
|
Jamie and Eddie: Souls of Strife (Short)
|
Writer, director, producer
|
2010
|
Evol
|
Writer, producer, director
|
2011
|
Mind Rush
|
Writer, producer, director
|
2012
|
Redemption
|
Writer, producer, director
|
2013
|
Mr. Q
|
Writer, producer, director,
|
2014
|
Double-Cross (Short)
|
Director
|
2014
|
The Banku Chronicles (Short)
|
Director, producer, writer
|
2015
|
Interception
|
Associate Producer, director
|
2015
|
Ghana Police (Short)
|
Writer, producer, editor, director
|
2016
|
Her First Time (Short)
|
Producer, director
|
2017
|
Black Rose
|
Producer, director, writer
|
Àwọn àmì-ẹ̀yẹ rẹ̀
Àwọn ìtọ́kasí
- ↑ "Double-Cross". October 31, 2014 – via www.imdb.com.
- ↑ "Pascal Aka wins Best Short Film at Accra Francophone Film Festival with Mr Q". Ghanaweb. Retrieved May 9, 2018.
- ↑ "Pascal Aka". Film Web. Retrieved May 9, 2018.
- ↑ "Jamie and Eddie: Souls of Strife". Movie Fone. Retrieved May 9, 2018.
- ↑ Givogue, Andre. "Ottawa EVOL Premiere". Andre Givogue. Archived from the original on May 9, 2018. Retrieved May 9, 2018.
- ↑ "Pascal AKA speaks on Double Cross movie". News Ghana. Retrieved May 9, 2018.
- ↑ "double cross credits". Nigeria List. Retrieved May 8, 2018.
- ↑ "Ghana Movie Awards 2014 (Full Nominations List)". Peacefm. Archived from the original on September 25, 2018. Retrieved May 8, 2018.
- ↑ Amoako, Julius. ""I turned down an offer to direct a porn movie" – Pascal Aka". Pulse.com.gh. Archived from the original on June 30, 2018. Retrieved May 8, 2018.
- ↑ "'Sakora' is a new thing – Pascal Aka". Ghanaweb. Retrieved May 9, 2018.
- ↑ "I Hate D-Black's Song – Pascal AKA". Peacefm. Archived from the original on May 10, 2018. Retrieved May 9, 2018.
- ↑ "Pascal Aka". IMDb.
- ↑ "Full List of the 2014 Ghana Movie Awards Winners – Joselyn Dumas, Adjetey Anang, Lil Win & Others". December 31, 2014. Archived from the original on October 13, 2020. Retrieved August 20, 2024.
- ↑ "Full List of the 2014 Ghana Movie Awards Winners – Joselyn Dumas, Adjetey Anang, Lil Win & Others". December 31, 2014. Archived from the original on October 13, 2020. Retrieved August 20, 2024.
- ↑ Adebambo, Adebimpe. "Review: Real Time International Film Festival Inaugural Lagos Edition – Omenka Online". www.omenkaonline.com. Archived from the original on 2021-11-10. Retrieved 2024-08-20.
- ↑ Mawuli, David. ""Her First Time": Pascal Aka"s short film wins "Best African Short Film" at 2016 RealTime Film Festival". Archived from the original on 2018-06-30. Retrieved 2024-08-20.
- ↑ "Finalists for Best Short Film Competition Announced – Lola Kenya Screen". www.lolakenyascreen.org.
- ↑ "Africa in Motion announces finalists for short film competition". www.ghanaweb.com.
|