Fatahu MuhammadFatahu Muhammad je olóṣèlú ọmọ orílè-èdè Nàìjíríà tinsójú àgbègbè ẹkùn ìdìbò Daura/Sandamu/Mai’adua ni ilé igbimọ aṣòfin àgbà orílè-èdè Nàìjíríà. O jẹ ọmọ bíbí ìpínlè Katsina. O kàwé parí láti ilé ìwé gíga Yunifásítì Ahmadu Bello ti o tí kò nípa ètò òṣèlú, ni ìlú Zaria. Wọn dibo yàn sì ilé igbimọ aṣòfin àgbà orílè-èdè Nàìjíríà nínú ètò ìdìbò ọdún 2019. Lọwọlọwọ ohùn ni adarí àgbá fún ẹka National Agricultural Seed Council (NASC) ipò ti aree Bola Ahmad Tinubu yàn sì ní 29th osu kẹta ọdún 2025. O lọ́wọ́ sí fífi òfin dé itakun abání dore Twitter ni ọdun 2021.[1] otún èrò re pa láti dára pò mọ ẹgbẹ òṣèlúAll Progressive Congress (APC),[2] O kùnà láti rí tikẹti ẹgbẹ òṣèlú náà gbà níbi ìdíje abele ẹgbẹ náà fún atun di ìbò.[3] Wọn dibo yàn Aminu Jamo láti rọ́pò rẹ ni ilé ìgbìmò aṣòfin àgbà. Itọkasi
|