Share to: share facebook share twitter share wa share telegram print page

Afo language

Eloyi
Afu
Sísọ níNigeria
Ọjọ́ ìdásílẹ̀2021
AgbègbèBenue State, Nassarawa State
Ìye àwọn afisọ̀rọ̀100,000
Èdè ìbátan
Àwọn àmìọ̀rọ̀ èdè
ISO 639-3afo

Èdè Eloyi, tàbí Afu (Afo) tàbí Ajiri,[1] jẹ́ èdè tí àwọn ará ilé Plateau ń sọ. Èdè yìí jẹ́ èdè tí àwọn ará Ìlú Eloyi ni Agatu àti Otukpo ni Ìpínlẹ̀ Benue àti Nassarawa ní Orílẹ̀ Èdè Nàìjíríà ń sọ.

Ìsòrí

Armstrong ní Ọdún (1955, 1983)[2][3] Pín Ede Eloyi tàbí Afo sí ìsòrí, ó pín sí abẹ́ Èdè Idomo, ṣùgbọ́n ìdánimọ̀ rẹ̀ yàtọ̀ èyí tí Armstrong padà ṣàfihàn iyèméjì.[4] àwọn ìgbìmò mìíràn pin sì abẹ́ Èdè Plateau. Àti pé Blench (2008) pin sábẹ́ ìsòrí mìíràn tí ó wà lábé Èdè ní Ìpínlẹ̀ Plateau [5].[6] Blench (2007) roò pé Eloyi jẹ́ onírúurú Èdè Plateau àmọ́ tí ó ní ipa Idomo èyí ó yẹ̀ kó jẹ́ ìdàkejì.[7]

Fonọ́lọ́jì

Kọ́ńsónántì

Kọ́ńsónántì[8]
Bilabial Labio-
dental
Alveolar Post-
alveolar
Palatal Velar Labial-
velar
Glottal
Plosive voiceless Àdàkọ:IPAlink Àdàkọ:IPAlink Àdàkọ:IPAlink Àdàkọ:IPAlink
voiced Àdàkọ:IPAlink Àdàkọ:IPAlink Àdàkọ:IPAlink Àdàkọ:IPAlink
Affricate Àdàkọ:IPAlink Àdàkọ:IPAlink
Fricative voiceless Àdàkọ:IPAlink Àdàkọ:IPAlink Àdàkọ:IPAlink Àdàkọ:IPAlink
voiced Àdàkọ:IPAlink Àdàkọ:IPAlink
Nasal Àdàkọ:IPAlink Àdàkọ:IPAlink Àdàkọ:IPAlink Àdàkọ:IPAlink
Rhotic Àdàkọ:IPAlink/Àdàkọ:IPAlink
Approximant Àdàkọ:IPAlink Àdàkọ:IPAlink Àdàkọ:IPAlink

Fáwẹ́lì

Vowels[9][10]
Front Central Back
Close Àdàkọ:IPAlink Àdàkọ:IPAlink
Close-mid Àdàkọ:IPAlink Àdàkọ:IPAlink
Open-mid Àdàkọ:IPAlink Àdàkọ:IPAlink
Open Àdàkọ:IPAlink

Àwọn Àkọsílẹ̀

  1. Hammarström, Harald; Forkel, Robert; Haspelmath, Martin; Bank, Sebastian (eds.). "Ajiri". Glottolog. 5.0. Archived from the original on 18 July 2024. Retrieved 2024-06-29.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  2. Blench 2007, citing Armstrong, R. G. (1955). "The Idoma-speaking peoples". In Forde, C. D.. Peoples of the Niger-Benue confluence. Ethnographic Survey of Africa. X. London: IAI. pp. 77–89. 
  3. Blench 2007, citing Armstrong, R. G. (1983). "The Idomoid languages of the Benue and Cross River Valleys". Journal of West African Languages 13 (1): 91–149. 
  4. Blench 2007, citing Armstrong, R. G. (1984). "The consonant system of Akpa". Nigerian Language Teacher 5 (2): 29. 
  5. Blench 2007, p. 5.
  6. Blench, Roger (2008-04-24). "Prospecting proto-Plateau" (PDF). Draft. Archived from the original (PDF) on 2014-04-07.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  7. Blench 2007, p. 26.
  8. Muniru et al. 2021, p. 21.
  9. Muniru et al. 2021, p. 22.
  10. Blench 2007, p. 2.
  11. Muniru et al. 2021, p. 23.

Àwọn Ìtọ́kasí

Àdàkọ:Platoid languages Àdàkọ:Volta-Niger languages


Àdàkọ:Plateau-lang-stub

Prefix: a b c d e f g h i j k l m n o p q r s t u v w x y z 0 1 2 3 4 5 6 7 8 9

Portal di Ensiklopedia Dunia

Kembali kehalaman sebelumnya